yo_php_text_ulb/01/20.txt

1 line
330 B
Plaintext

\v 20 Nípasẹ̀ àfojúsùn mi àti ìrètí tí ó dájú wípé ojú kì yóò tì mí rárá, pẹ̀lú gbogbo ìgboyà, nísinsìnyí gẹ́gẹ́ bíi ti tẹ́lẹ̀ pe, a ó gbé Krístì ga lára mi, ní yíyè tàbí ní kíkú. \v 21 Nítorí fún mi láti wà láàyè jẹ́ fún Krísti láti kú sì jẹ́ èrè.