Wed Jul 03 2019 09:03:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-03 09:03:21 +01:00
parent 998eb18ac9
commit d4e8a6e247
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 \v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 Kìkì pé kí ẹ̀yin kí ó má gbé ìgbé-ayé yín ní ìbámu pẹ̀lú ìhìnrere Krístì.