Wed Oct 23 2019 04:59:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
e6fa15e7ae
commit
bc02ab555a
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pàdé ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ Rẹ̀ nínú ògo nínú Krístì Jésù. \v 20 Ǹjẹ́ nísinsìnyí ògo ni fún Ọlọ́run àti Bàbá wa láí àti láíláí. Àmín
|
||||
\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pàdé ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ Rẹ̀ nínú ògo nínú Krístì Jésù. \v 20 Ǹjẹ́ nísinsìnyí ògo ni fún Ọlọ́run àti Bàbá wa láí àti láíláí. Àmín.
|
Loading…
Reference in New Issue