Wed Jul 03 2019 09:29:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-03 09:29:21 +01:00
parent f9874983bf
commit 5c4c48eec2
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú ọkàn kan. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìhìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn yóò pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè.
\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú inú-rere. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìhìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn yóò pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè.