diff --git a/01/25.txt b/01/25.txt index 1c09310..20221c3 100644 --- a/01/25.txt +++ b/01/25.txt @@ -1 +1 @@ -\v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 Kìkì pé kí ẹ̀yin kí ó má gbé ìgbé-ayé yín ní ìbámu pẹ̀lú ìhìnrere Krístì, tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bóyá mo wá wò yín tàbí n kò wá, èmi yóò lè máa gbọ́ nípa yín, pé ẹ̀ \ No newline at end of file +\v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 Kìkì pé kí ẹ̀yin kí ó má gbé ìgbé-ayé yín ní ìbámu pẹ̀lú ìhìnrere Krístì, tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bóyá mo wá wò yín tàbí n kò wá, èmi yóò lè máa gbọ́ nípa yín, pé ẹ̀ ń dúró ṣinṣin pẹ̀lú ẹ̀mí kan, ẹ sì ń lépa papọ̀ fún ìgbàgbọ́ \ No newline at end of file