From 5364b133a1b666a8f749ef6bea1c4ae7b372befc Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Fri, 5 Jul 2019 10:21:45 +0100 Subject: [PATCH] Fri Jul 05 2019 10:21:45 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 02/25.txt | 2 +- 02/28.txt | 1 + 2 files changed, 2 insertions(+), 1 deletion(-) create mode 100644 02/28.txt diff --git a/02/25.txt b/02/25.txt index 1eb29e7..2a98cc7 100644 --- a/02/25.txt +++ b/02/25.txt @@ -1 +1 @@ -\v 25 Ṣùgbọ́n mo rò pé ó yẹ kí n rán Ẹ̀páfródítù padà sí yín. Arákùnrin mi ni, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi ni, akẹgbẹ́-ọmọ-ogun ni pẹ̀lú mi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ìráńṣẹ́ yín tí ó ń mójútó àwọn àìní mi. \v 26 Nítorí tí ọkàn rẹ̀ pòrurù gidi gan, ó sì ń jarán láti wà pẹ̀lú yín nítorí tí ẹ gbọ́ pé ara rẹ̀ kò yá. \v 27 Lóòótọ́ ni pé ó ṣe àìsàn dé ojú ikú. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ṣàánú fún un, kì í sì ṣe fún òhun nìkan, ṣùgbọ́n fún èmi náà, \ No newline at end of file +\v 25 Ṣùgbọ́n mo rò pé ó yẹ kí n rán Ẹ̀páfródítù padà sí yín. Arákùnrin mi ni, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi ni, akẹgbẹ́-ọmọ-ogun ni pẹ̀lú mi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ìráńṣẹ́ yín tí ó ń mójútó àwọn àìní mi. \v 26 Nítorí tí ọkàn rẹ̀ pòrurù gidi gan, ó sì ń jarán láti wà pẹ̀lú yín nítorí tí ẹ gbọ́ pé ara rẹ̀ kò yá. \v 27 Lóòótọ́ ni pé ó ṣe àìsàn dé ojú ikú. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ṣàánú fún un, kì í sì ṣe fún òhun nìkan, ṣùgbọ́n fún èmi náà, kí ìbànújẹ́ mi má baà peléke síi. \ No newline at end of file diff --git a/02/28.txt b/02/28.txt new file mode 100644 index 0000000..38c70c4 --- /dev/null +++ b/02/28.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 28 \v 29 \v 30 m \ No newline at end of file