Wed Oct 23 2019 03:53:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
386295fd50
commit
24240bdb28
|
@ -1 +1 @@
|
||||||
\c 4 \v 1 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi olùfẹ́ tí ọkàn mi ń ṣe àfẹ́rí, ayọ̀ mi àti adé mi, báyìí ni kí ẹ̀yin dúró ṣinṣin nínú Olúwa, ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi ọ̀wọ́n. \v 2 Mò ń rọ Éúódíà, mo sì ń bẹ Síńtíkè, ẹ ní ọkàn kan náà nínú Olúwa. \v 3 Bẹ́ẹ̀ sì ni mò ń rọ ìwọ náà pẹ̀lú, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi tòótọ́: ran àwọn obínrin wọ̀nyí lọ́wọ́. Nítorí wọ́n ṣe làálàá pẹ̀lú mi fún ìtànkálẹ̀ ìhìnrere pẹ̀lú Klẹ́mẹ́ńtì àti àwọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi yòókù tí orúkọ wọn wà nínú Ìwé Ìyè.
|
\c 4 \v 1 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi olùfẹ́ tí ọkàn mi ń ṣe àfẹ́rí, ayọ̀ mi àti adé mi, báyìí ni kí ẹ̀yin dúró ṣinṣin nínú Olúwa, ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi ọ̀wọ́n. \v 2 Mò ń rọ Éúódíà, mo sì ń bẹ Síńtíkè, ẹ ní ọkàn kan náà nínú Olúwa. \v 3 Bẹ́ẹ̀ sì ni mò ń rọ ìwọ náà pẹ̀lú, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi tòótọ́: ran àwọn obínrin wọ̀nyí lọ́wọ́. Nítorí wọ́n ṣe làálàá pẹ̀lú mi fún ìtànkálẹ̀ ìhìnrere pẹ̀lú Klẹ́mẹ́ńtì àti àwọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi yòókù tí orúkọ wọn wà nínú Ìwé Ìyè Náà.
|
Loading…
Reference in New Issue