adesinaabegunde_yo_php_text.../03/17.txt

1 line
536 B
Plaintext

\v 17 Ẹ má a ṣe àfarawé mi, ẹ̀yin ará. Ẹ má a ṣe àkíyèsí àwọn tí wọ́n ń rin déédé pẹ̀lú àpẹrẹ tí ẹ ní nínú wa. \v 18 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńrìn -- àwọn tí mo ti máa ńsọ nípa wọn fún un yín, tí mo sì tún sọ fún un yín báyìí pẹ̀lú omijé -- bí àwọn ọ̀tá àgbélèbú Krístì. \v 19 Ìparun ni àtunbọ̀tán wọn. Nítorí ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú àwọn ohun ìtìjú wọn. Ohun ayé ti gba ọkàn wọn.