adesinaabegunde_yo_php_text.../03/01.txt

1 line
525 B
Plaintext

\c 3 \v 1 Níparí, ẹ̀yin ará mi, ẹ yọ̀ nínú Olúwa. Kò ni mí lára láti kọ̀wé àwọn nǹkan woǹyí kan nán aǹ sí yín lẹ́kàn náà si. Àwọn nǹkan wọ̀nyí yíò pa yín mọ́. \v 2 Ẹ ṣọ́ra fún àwọn ajá. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn oníṣẹ́ ibi. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn tí wọ́n ń panilára. \v 3 Nítorí àwa ni olùkọlà. Àwa ni à ń sìn nípa Ẹ̀mí Ọlọ́run. Àwa ni à ń ṣògo nínú Krístì Jésù, tí a kò sì gbékẹ̀lé ẹran ara.