adesinaabegunde_yo_php_text.../02/17.txt

1 line
264 B
Plaintext

\v 17 Ṣùgbọ́n bí a bá tilẹ̀ tú mi jáde mí bíi ọrẹ sórí ẹbọ àti iṣẹ́ ìsìn ìgbàgbọ́ yín, èmí yọ̀, èmí yóò sì yọ̀ pẹ̀lú gbogbo yín. \v 18 Bákannáà kí ẹ̀yin kí ó yọ̀, kí ẹ sì yọ̀ pẹ̀lú mi.