From e6fa15e7ae4c686a83ab5657d4dec1aa3477f760 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Wed, 23 Oct 2019 04:57:13 +0100 Subject: [PATCH] Wed Oct 23 2019 04:57:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 04/18.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/04/18.txt b/04/18.txt index ad8be0a..16303a2 100644 --- a/04/18.txt +++ b/04/18.txt @@ -1 +1 @@ -\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pàdé ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ Rẹ̀ nínú ògo nínú Krístì Jésù. \v 20 \ No newline at end of file +\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pàdé ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ Rẹ̀ nínú ògo nínú Krístì Jésù. \v 20 Ǹjẹ́ nísinsìnyí ògo ni fún Ọlọ́run àti Bàbá wa láí àti láíláí. Àmín \ No newline at end of file