Wed Oct 23 2019 04:33:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:33:13 +01:00
parent 93df90c71e
commit 1cdbe3b075
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Mo yọ̀ gidigidi nínú Olúwa nítorí nísinsìnyí, lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, ẹ ti sọ àníyán yín fún mi dọ̀tun. Lóòótọ́ ni ọrọ mí ti ká yín làra tẹ́lẹ, ṣùgbọ́n ẹ kò ní àǹfàní láti ṣe ìrànlọ́wọ́. \v 11 Èmi kò sọ èyí nítorí pé mo ṣe aláìní. Nítorí mo ti kọ́ láti ní ìtẹ́lọ́rùn nínu ipòkípò tí mo bá wà. \v 12 Mo mọ ohun tí ó pè fún láti ṣe àìní, bẹ́ẹ̀ sì ni mo mọ ohun tí ó pè fún láti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Ní gbogbo ọ̀nà àti nínú ohun gbogbo mo ti kọ́ bí a ṣe ń jẹ àjẹyó tàtí bí a ṣe ń wà lébi, bí a ṣe ń wà nínú ọ̀pọ̀ tàbí bí a ṣe ń ṣe a \v 13
\v 10 Mo yọ̀ gidigidi nínú Olúwa nítorí nísinsìnyí, lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, ẹ ti sọ àníyán yín fún mi dọ̀tun. Lóòótọ́ ni ọrọ mí ti ká yín làra tẹ́lẹ, ṣùgbọ́n ẹ kò ní àǹfàní láti ṣe ìrànlọ́wọ́. \v 11 Èmi kò sọ èyí nítorí pé mo ṣe aláìní. Nítorí mo ti kọ́ láti ní ìtẹ́lọ́rùn nínu ipòkípò tí mo bá wà. \v 12 Mo mọ ohun tí ó pè fún láti ṣe àìní, bẹ́ẹ̀ sì ni mo mọ ohun tí ó pè fún láti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Ní gbogbo ọ̀nà àti nínú ohun gbogbo mo ti kọ́ bí a ṣe ń jẹ àjẹyó tàtí bí a ṣe ń wà lébi, bí a ṣe ń wà nínú ọ̀pọ̀ tàbí bí a ṣe ń ṣe aláìní. \v 13 Mo lè ṣe ohun gbogbo nípasẹ̀ Ẹnití ó fi okun fún mi.