adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/19.txt

1 line
359 B
Plaintext

\v 19 Lẹ́yìn tí olúwa ti báwọn sọ̀rọ̀ tán, a gbà á lọ sí ọ̀run ó sì jókòó sí ọwọ́ ọ̀tùn Ọlọ́run \v 20 Àwọn ọmo ẹ̀yìn kúrò wọ́n sì ń wásù níbi gbogbo, nígbàtí Olúwa ń bá wọn sisẹ́, ó sì ń fi ìdí ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀ nípa isẹ́ àmìn tí ó ń tèle wọn