adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/41.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 41 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́ẹ̀wá yó kù gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí Jákọ́bù àti Jòhánnù. \v 42 Jésù pè wọ́n sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ó wípé, "ẹ̀yín mọ̀ pé àwọn tí a kà sí olórí láàrín àwọn kèfèrí má ńlo ipá lórí wọn àti àwọn alásẹ àgbà ńlo ipò àsẹ lórí wọn