adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/38.txt

1 line
550 B
Plaintext

\v 38 Jésù dá wọn lóhùn, ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀yin ńbèrè. Ẹ̀ yín a le mu ife tí èmi yóò mu tàbí farada ìtẹ̀bọmi tí a ó fi rì mí bọmi?" \v 39 Wọ́n wí fún pé, "àwa leè sé" Jésù wí fún wọn pé , ife tí èmi yóò mu ni ẹ̀yin náà yóò mu àti ìtẹ̀bọmi tí èmi ó se ni aó se fún ẹ̀yin náà. \v 40 Sùgbọ́n, ẹni tí yóò jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ òsì mi, kìí se tèmi láti fúnni bíkòse àwọn tí a ti pèsèe rẹ̀ sílẹ̀ fún."