adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/35.txt

1 line
415 B
Plaintext

\v 35 Jákọ́bù àti Jòhánnù, àwọn ọmọ Sébédè gòkè wá sọ́dọ́ rẹ̀ wọ́n wípé, "Olùkọni, àwa fẹ́ kí ẹ se ohunkóhun tí a bá bèrè fún wa" \v 36 Ó bi wọ́n pé, kínni ẹ fẹ́ kí èmi ó se fún yín?" \v 37 " Wọ́n wípé, gbà wá láàyè láti jókòó pẹ̀lú rẹ nínú ògo, ọ̀kan lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ àti èkejì ní ọwọ́ òsì rẹ."