adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/23.txt

1 line
530 B
Plaintext

\v 23 Jésù sí wo àyíká ó wí fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, "báwo ni yó ti nira tó fún àwọn ọlọ́rọ̀ láti wọ íjọba Ọlọ́run! \v 24 "Ẹnú ya àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí àwọn ọ̀rọ̀ọ rẹ̀. Sùgbọ́n Jésù tún sọ fún won lẹ́ẹ̀kan si, " Ẹ̀ yin ọmọdé, báwo ni yó se nira tó láti wọ ìjọba Ọlọ́run! \v 25 Ó rọrùn fun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ láti gba ojú abẹ́rẹ́ wọlé jù fún ọlọ́rọ̀ kan láti wọ ìjọba Ọlọ́run"