1 line
383 B
Plaintext
1 line
383 B
Plaintext
\v 36 Jésù kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n máse sọ fún ẹni kankan. Sùgbọ́n bí Ó ti ń kìlọ̀ fún wọn tó bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sì ń polongo Rẹ̀ síi. \v 37 Ẹnu ya àwọn ènìyàn kọjá gidigidi, wọ́n sì ń wípé, "Ó ti se gbogbo ǹkan dáradára. Ó mú kí adití gbọ́ràn, Ó sì mú kí ẹnití kò le soro di eniti nsoro." |