\v 9 O si ran awọn ọmọ ẹyin rẹ pe ki wọn ki o seeto ọkọ̀ oju omi kekere kan silẹ fun ohun nitori ọ̀pọ̀ eniyan, ki wọn ki o ma ba tẹẹ pa. \v 10 Nitori ti o ti wo ọpọ eniyan san ẹnikọọkan ti o ni ìpónjú n gbìyàjú lati fi ọwọ kan an bi o ti wu ki o ri.