\v 12 \v 13 Won si jade lo lati kede pe ki awon eniyan yipada kuro ninu ese won. Won le emi esu jade, won wo awon alaisan san nipa ami ifororo yan.