1 line
440 B
Plaintext
1 line
440 B
Plaintext
\v 38 Nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ Jésù wípé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin, tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà \v 39 àti ibùjókòó ọlá nínú Sinagọgu àti ipò ọlá níbi àsè. \v 40 Wọ́n a tún máa jẹ ilé àwọn opó rún, tí wọ́n sì ń gbàdúrà gígùn fún àsehàn. Àwọn wọ̀nyí yíò wa ìdálẹ́bi púpọ̀." |