adesinaabegunde_yo_mrk_text.../12/18.txt

1 line
352 B
Plaintext

\v 18 Nígbànáà ni àwọn Sadusí, tí ó wípé kò sí àjíǹde, tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n biì léèrè pé, \v 19 “Olùkọ́, Mose fún wa ní òfin pé, 'Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà.