adesinaabegunde_yo_mrk_text.../12/10.txt

1 line
511 B
Plaintext
Raw Blame History

This file contains invisible Unicode characters

This file contains invisible Unicode characters that are indistinguishable to humans but may be processed differently by a computer. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

This file contains Unicode characters that might be confused with other characters. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

\v 10 Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ka ẹsẹ yìí nínú ìwé mímọ́? Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, òun náà ni ó di pàtàkì igun ilé. \v 11 Èyí wá láti ọdọ̀ Olúwa, ó sì jẹ́ ìyàlẹ́nu lójú tiwa?” \v 12 Wọ́n ń wá ọnà láti mú Jesu, ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà wọ́n nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń pòwe mọ́. Nítorí náà wọ́n fi í sílẹ̀ lọ.