1 line
525 B
Plaintext
1 line
525 B
Plaintext
\v 11 NÍgbà náà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. \v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” \v 13 Nígbà náà ni fi wọ́n sílẹ̀, ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà. |