adesinaabegunde_yo_mrk_text.../08/05.txt

1 line
400 B
Plaintext

\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?” Wọ́n wípé, “Méje.” \v 6 Ó pàṣẹ fún ọ̀pọ ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó mú àkàrà méje náà, ó dúpẹ́, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́. Ó fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé sí iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.