adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/24.txt

1 line
358 B
Plaintext

\v 24 Ó wí fún wọn pé, “Ẹ máa kíyèsi ohun tí ẹ bà gbọ́, nítorí òṣùwọ̀n tí ẹ̀yin bá fi wọ́n náà ni a ó fi wọ́n fún un yín, a ó sì tún fi kún n fún n yín. \v 25 Nítorí ẹni tí ó bá ní, òun ni a ó tún fi fún sí i, àti lọ́wọ́ ẹni tí kò bá ní, ni a ó ti gba èyí náà tí ó ní.”