adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/29.txt

1 line
401 B
Plaintext

\v 29 Nígbà tí wọn sì jáde kúrò nínú Sínágọ́gù, wọ́n lọ sí inú ilé Símónì àti Áńdérù pẹ̀lú Jákọ́bù àti Jòhánù . \v 30 Ìyá- ìyàwó Simoni tí ó dùbúlẹ̀ àìsàn ibà, wọ́n sì sọ fún Jésù nípa rẹ̀. \v 31 Ó sì wá, ó fà á lọ́wọ́, ó sì gbé e dìde; ibà náà si fi sílẹ̀, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.