\v 27 Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ń bi ara wọn pé, "Irú kíni èyí? Ẹ̀kọ́ tuntun pẹ̀lú àsẹ? Ó tún pàṣẹ fún àwọn ẹ̀mí àìmọ́ wọ́n sì gbọ́ tirẹ̀!.” \v 28 Ìròyìn nípa rẹ̀ tàn ká gbogbo agbègbè Galili.