adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/19.txt

1 line
336 B
Plaintext

\v 19 Bí Jésù sì ti rìn síwájú díẹ̀, Ó rí Jakọbu ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀, wọ́n wa nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe. \v 20 Ó ké wọn, wọ́n sì fi Sébédè baba wọn sílẹ̀ nínú ọkọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbàṣe, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.