adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/16.txt

1 line
362 B
Plaintext

\v 16 Nígbà ti ó ń rìn létí Òkun Galili, Ó rí Simoni àti Anderu arákùnrin rẹ̀, wọ́n ń fi àwọ̀n wọn pẹja, torí pé apẹja ni wọ́n. \v 17 Jesu sì wí fún wọn pé, “Ẹ wa, ẹ tẹ̀lé mi, Èmi yóò sì sọ yín di apẹja ènìyàn.” \v 18 Ní kánkán wọ́n fi àwọ̀n wọn sílẹ̀, wọ́n sì tẹ̀lé e.