adesinaabegunde_yo_mrk_text.../12/35.txt

1 line
585 B
Plaintext
Raw Blame History

This file contains invisible Unicode characters

This file contains invisible Unicode characters that are indistinguishable to humans but may be processed differently by a computer. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

This file contains Unicode characters that might be confused with other characters. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

\v 35 Jesu dáhùn nígbà tí ó ń kọ́ ni nínú tẹ́ḿpílì, ó wípé, “Èéṣe tí àwọn olùkọ́ òfin fi wí pé Kristi ní ọmọ Dáfídì? \v 36 Dáfídì tìkára rẹ̀, nípa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé, “Olúwa sọ fún Olúwa mi pé,“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.' \v 37 Dáfídì tìkára rẹ̀ pè é ní Olúwa, Báwo ni Olúwa tún ṣe lè jẹ́ ọmọ Dáfídì?” Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì fi ayọ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀.