adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/39.txt

1 line
388 B
Plaintext

\v 39 Nígbàtí Ò sí wọ ilé náà, Ó wí fún wọ́n wípé, "Kí lódé tí ẹ ń banújẹ́ tí ẹ ṣì ńsọkún? Ọmọ náà kò kú, sùgbọ́n ó sùn." \v 40 Wọ́n sì fi rẹ́rin. Sùgbọ́n Ó ti gbogbo wọ́n si ta. Ó sì mu baba ọmọ náà, ìyá ọmọ náà àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, Ó sì wọ́lè sí ibi tí ọmọ náà wa.