adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/25.txt

1 line
417 B
Plaintext

\v 25 Obìnrin kan sí wá ní bẹ tí o ní isun ẹ̀jẹ̀ fún ọdún méjìlá. \v 26 Ó tí ní orísiríìsi ìlàkọjá pẹ̀lú àwon onísègùn àti pé ó ti ná ohun gbogbo tí óní, sùgbọ́n, kàkà kí o sàn se ló ń le koko si. \v 27 Nígbàtí o sì gbó ìròyìn nípa Jésù, ò sí tọ̀ wá larin àwon èrò, ò dúró lẹ́yìn rẹ̀, ó sì fi ọwọ́ kan etí asọ Rẹ̀.