adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/13.txt

1 line
460 B
Plaintext

\v 13 Ó sì wí fún wọn pé, “Sé òwe yìí kò yé e yín ni? Báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe mọ ìtumọ̀ àwọn òwẹ mìíràn? \v 14 Afúnrúgbìn tí ó ǹ fúnrúgbìn ni ó ń fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ náà. \v 15 Èyí ǐ ni àwọn tó bọ́ sí ojú ọ̀nà, níbi tí a fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ sí, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà èṣù wá ó sì mú ohun tí wọ́n ti gbìn kúrò.