|
\v 17 Jákọ́bù ọmọ Zébédè ati Jòhánù arákùnrin Jákọ́bù, àwọn ẹni tí ó pè ní Bòánájì, èyí tí ó túmọ̀ sí, àwọn ọmọ àrá; \v 18 ati Áńdérù, Fílípì, Batolómíù, Mátíù, Tọ́másì, Jákọ́bù ọmọ Áfáúsì, Tádáúsì, Símónì alàjàgbara \v 19 ati Júdásì Ìskáriọ́tù, ẹni tí yoò fií hàn. |