adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/11.txt

1 line
203 B
Plaintext

\v 11 Nigba kuu gba ti awọn ẹ̀mì aìmọ́ ba ri, wọn a tẹriba niwaju rẹ pẹlu ariwo, wọn a wipe, "Iwọ ni Ọmọ Olórun." \v 12 O si pa wọn lẹnu mọ pe ki wọn maa se fi oun han.