adesinaabegunde_yo_mrk_text.../13/07.txt

1 line
414 B
Plaintext

\v 7 Nígbàtí ẹ̀yin bá ń gbọ́ ìró ogun tàbí àwọn ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ogun, ẹ máṣe ṣe àníyàn; àwọn ǹkan wọ̀nyí gbọdọ̀ ṣẹlẹ̀, ṣùgbọ́n òpin kò ì tí dè. \v 8 Nítorí orílẹ̀èdè yíò dìde sí ara wọn, àti ìjọba lòdì sí ìjọba. Ilẹ̀ ríru yóò wà ní ọpọ̀lọpọ̀ ibi, àti ìyaǹ. Ǹwọ̀nyí ni ìbẹ̀rẹ̀ ìpọ́njú.