adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/19.txt

1 line
360 B
Plaintext

\v 19 Lẹ́yìn tí Olúwa ti báwọn sọ̀rọ̀ tán, a gbà á lọ sí ọ̀run, ó sì jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run. \v 20 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn kúrò wọ́n sì ń wásù níbi gbogbo, nígbàtí Olúwa ń bá wọn ṣiṣẹ́, ó sì ń fi ìdí ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀ nípa iṣẹ́ àmìn tí ó ń tẹlẹ wọn.