adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/12.txt

1 line
272 B
Plaintext

\v 12 Lẹ́hìn ǹkan wọ̀nyí ó farahàn ní orísirísi ọ̀nà fún méjì nínú wọn bí wọ́n sé ń jáde lọ sí inú orílẹ̀ èdè náà. \v 13 Wọ́n lọ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn tó kù, sùgbọ́n wọn kò gbà wọ́n gbọ́.