adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/09.txt

1 line
434 B
Plaintext

\v 9 Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ní ọjọ́ ìkíní ọ̀sẹ̀, lẹ́yìn tí ó ti jí dìde, ó kọ́kọ́ farahàn Màríà Magdalénì, lára ẹni tí ó ti lẹ́ ẹ̀mí èsù méje jáde. \v 10 Ó lọ sọ fún àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, níbi tí wọ́n tí ń sọ̀fọ̀ tí wọ́n sì ń sọkún. \v 11 Wón gbọ́ pé ó wà láàyè àti pé ó ti rí i, sùgbọ́n wọn kò gbàgbọ́