adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/08.txt

1 line
197 B
Plaintext

\v 8 Wọ́n jáde wọ́n sì sá kúrò nínú ibojì náà; ẹ̀rù bà wọ́n, ẹnu sì yà wọ́n. Wọ́n kò sọ ohunkóhun fún ẹnikẹ́ni nítorítí ẹ̀rù bà wọ́n gidi gan.