adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/05.txt

1 line
541 B
Plaintext

\v 5 Wón wọ inú ibojì náà, wọ́n sì rí ọmọdékùnrin kan tí ó wọ asọ funfun, jókọ ní ọwọ́ ọ̀tún, ẹnú sì yàwọ́n. \v 6 Ó wí fún wọn pé , "Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ̀yin ń wá Jésù ará Násárẹ́tì, Ẹni tí a kàn mó àgbélèbú. Ó ti jí dìde. Kòsí ní ìhín. Ẹ wo ibi tí a tẹ́ sí. \v 7 Sùgbọ́n ẹ lọ, sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti Pétérù pé ó ti síwájú yín lọ sí Gálílì. Níbẹ̀ ni ẹ̀yin yóò ri, bí ó ṣe sọ fún yín."