adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/03.txt

1 line
221 B
Plaintext

\v 3 Wọ́n ńbá ara wọ́n sọ̀rọ̀, wípé tani yóò yí òkúta kúrò lẹ́nu ibojì nàà? \v 4 Nígbàtí wọ́n gbójú wo òkè, wọ́n rí pé a ti yí òkúta náà kúrò, nítorí tí ó tóbi gan.