adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/69.txt

2 lines
381 B
Plaintext

\v 69 Ọmọbìnrin nǎ sì tún rí i, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ fún àwọn tí ó dúró níbẹ̀ pẹ́, "Ọ̀kan nínú wọn ni okùnrin yî.
\v 70 Ó sì tún sẹ́ ẹ. Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, àwọn tí ó dúró níbẹ̀ tún wí fún Pétérù pé, "Lóòtọ́ ni, ọ̀kan nínú wọn ní ìwọ íṣe, nítorípé ará Gálílì ni ìwọ náà.