adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/66.txt

2 lines
458 B
Plaintext

\v 66 Bí Pétérù sì ti wà ní ìsàlẹ̀ ní àafin, ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin olórí àlùfáà wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.
\v 67 Ó rí Pétérù tí ó ńyáná, ó tẹjú mọ́ ọ, ó sì wípe, ìwọ́ wà pẹ̀lú Jésù aráa Násárẹ́tì yí. \v 68 Ṣùgbọ́n ó sẹ́ ẹ, ó wípé, "Èmi kò mó bẹ́ẹ̀ni òye ohun tí ìwọ ńsọ kò tilẹ̀ yé mi." Ó sì jáde lọ sí àgbàlá. Àkùkọ sì kọ.