adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/60.txt

1 line
474 B
Plaintext

\v 60 Olórí àlùfáà sì dìde láarín wọn ó sì bi Jésù lêrè wípé, Ìwọ kò ní ìdáhùn bí, kíni ohun tí àwọn ènìyàn yín jẹ́rǐ lòdì sí ọ? \v 61 Ó sì dákẹ́, kò sì so ohunkóhun. Olórí àlùfáà sì bií lêrè wípé, "sé ìwọ ni Krístì ọmọ olùbùkún?" \v 62 Jésù wípé, "Èmi ni; ìwọ yíò sì rí ọmọ Ènìyàn nígbàtì ó bá jókǒ ní apá ọ̀tún agbára tí ó sì wà ní àwọ sánmọ̀."