adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/47.txt

1 line
581 B
Plaintext

\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn tí ó sún mọ́ wọn yọ idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà. \v 48 Jésù sì wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó fé mú olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbà gbogbo tí mo sì ń kọ́ọ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ sẹ." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jésù sì fií sílẹ̀ wọ́n sì sá lọ.