adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/43.txt

1 line
548 B
Plaintext

\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Ẹnikẹ́ni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Júdásì sì dé, lójúkanńà ó tọ Jésù wá ó sì wípé, "Olùkọ́," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.