adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/40.txt

1 line
425 B
Plaintext

\v 40 Ó sì tún bá wọn tí wọn ń sùn, nítorí tí ojú wọn wúwo wọn kó sí mọ ohun tí wọn yí ò sọ fún n. \v 41 Ó sì wá ní ìgbà kẹta ó sì wí fún wọn pé, " Sé ẹ̀yin sí n sùn ni? Ó ti tó! Wákàtí náà ti dé. Wò ó! Ati fi ọmọ ènìyàn lé àwọn ẹlẹ́sẹ̀ lọ́wọ́. \v 42 Ẹ dìde; ẹ jẹ́kí á lọ. Wó ò, ẹni tí yíò dà mí ti wà nítòsí."