adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/37.txt

1 line
453 B
Plaintext

\v 37 Ó padà wá, ó sì rí wọn tí wón n sùn, ó sì wí fún Pétérù, "Símónì, ìwọ ń sùn bi? Ìwọ kò ha le sọ́nà fún wákàtí kan? \v 38 Ẹ máa sọ́nà kí e sì ma gbàdúrà kí ẹ̀yin kí ó má baà bọ́ sínú ìdánwò. Ẹ̀mí ń fẹ́ nítòótọ́, ṣùgbọ́n ó se àìlera fún ara." \v 39 Ó sì tún lọ kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn láti lọ gbàdúrà, ó sì tún lo ọ̀rọ̀ kanńà.